Egba Anthem (Yoruba)
Lori oke o’un petele Ibe l’agbe bi mi o
Ibe l’agbe to mi d’agba oo Ile ominira
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo
Abeokuta ilu Egba N ko ni gbagbe e re
N o gbe o l’eke okan mi Bii ilu odo oya
Emi o f’Abeokuta sogo N o duro l’ori Olumo
Maayo l’oruko Egba ooo Emi omoo Lisabi
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo
Emi o maayo l’ori Olumo, Emi o s’ogoo yi l’okan mi
Wipe ilu olokiki o, L’awa Egba n gbe
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo
Egba Anthem (English)
Atop the mountains and the valleys there, I was born
Such is the place where I was brought up the land of freedom.
Chorus: Rejoice, rejoice, rejoice on Olumo Rock, Rejoice, rejoice, rejoice atop the Rock of Olumo
I will make Abeokuta my glory I will stand tall on Olumo Rock Rejoice in the name of Egba I, a child of Lisabi.
Chorus: Rejoice, rejoice, rejoice on Olumo Rock, Rejoice, rejoice, rejoice atop the Rock of Olumo.
Abeokuta, the Land of the Egba, I will etch you on my heart Like the land beyond the Niger River I will continue to rejoice on top of Olumo Rock I will make this glory in my heart that it is in a famous town that the Egba people dwell
Chorus: Rejoice, rejoice, rejoice on Olumo Rock, Rejoice, rejoice, rejoice atop the Rock of Olumo.